Kareem Warris: Ọmọ kekere tó di àwòmáleèlọ ládugbò

Àkọlé fídíò, 'Mo fẹ́ di ẹni gíga'

Kareem Warris ti ya ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwòrán tó sí ní orúkọ àti ìtumọ̀ fún àwòrán kọ̀ọ̀kan.

Koda, o ti ya aworan aarẹ ilẹ Faranse, Emmanuel Macron lasiko abẹwo rẹ si Nigeria.

Idi ree ti ijọba ipinlẹ Eko fi fun ni amin ẹyẹ.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: