Somolu Printing Press: Ṣhómólú l‘Eko: Ibùdó ìwé títẹ̀ àkọ́kọ́ ní W.Afrika

Àkọlé fídíò, Shomolu gbajúmọ̀ fún ìwé títẹ̀

BBC Yorùbá dé àdúgbò Sómólú ní ìlú Èkó, níbi tí ọ̀pọ̀ ilé ìtẹ̀wé pọ̀ sí jùlọ ní ẹkùn ìwọ̀ òòrùn Afrika.

A gbọ́ pé ìwé títẹ̀ ní Sómólú dára ju èyí tí wọn tẹ̀ ní ilẹ̀ òkèèrè bíi orílẹ̀-èdè China lọ.

Sùgbọ̀n àwọn òǹtẹ̀wé ní Sómólú ti ń pariwo pé bí ìjọba se ń gbé isẹ́ ìwé títẹ̀ lọ sí China ń pa àwọn lára.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: