You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Olatunji James alákàrà Ó ta lẹ́nu: Ìwọ tó o bá ń tijú, o ò le dé 'bi gíga
Ọlátúnjí James, tí wọn tún ń pè ní Alákàrà tó ta lẹ́nu sọ fún BBC Yorùbá pe ilé ẹ̀kọ́ gbogbo-nse Poly tìpínlẹ̀ Ọ̀sun ni òun ti kẹ́kọ̀ọ́ nípa òkoòwò, ìyẹn Business Administration.
James ni o sú òun láti da ìjọba láàmú fún isẹ́ osù ló mú kí òun máa dín àkàrà tà.
Ò wá gba àwọn ọ̀dọ́ ní ìmọ̀ràn láti ronú bí wọn yóò se gba àwọn èèyàn sísẹ́, dípò kí wọn máa wá isẹ́ kiri lọ.
Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:
- Àwọn nǹkan mẹ́ta tí a kò tíì mọ̀ nípa Covid-19 lẹ́yìn tí àrùn náà bẹ́ sílẹ̀ rèé
- Dangote, má ṣe dáwọn ọ̀dọ́ tó ní kó dupò ààrẹ lọ́dún 2023 lóhùn o- Shehu Sani
- Àwọn ọ̀dọ́ ló mọ ìtumọ̀ 'Problem' - Remilekun Abdulkalid Safaru
- Ogbologbo ijapa l'aafin Sọun
- Èrò àwọn ọmọ Nàìjíríà ṣọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ bí wọ́n ṣe rí Abba Kyari, Obi Cubana níbi ìgbéyàwò ọmọ ọ̀gá ọlọ́pàá Alkali Baba
- Igbe àyé Ọbáfẹ́mi Awólọ̀wọ́ nigba aye rẹ̀