You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Reminisce: Àwọn ọ̀dọ́ ló mọ ìtumọ̀ orin 'Problem'- Remilekun Abdulkalid Safaru, Alaga Baba Afusa
Remilekun Abdulkalid Safaru (Reminisce) sọ pé ọ̀pọ̀lọpọ̀ ni kò ní òye nípa orin tí òun ń kọ.
Ó ní òun kò sépè rárá nínú orin tí òun ń kọ sùgbọ́n àwọn ọ̀dọ́ nìkan ni ìtumọ̀ orin náà yé.
Reminisce ní òun kìí gbé ìgbé ayé òpùrọ́ táa mọ̀ sí ‘fake life’.
Ó ní gbogbo oore tí Ọlọrun se fún òun, ló tẹ́ òun lọ́rùn.