You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Ògbólógbòó Ìjàpá tó máa ń sọ̀rọ̀ bí ènìyàn
Ijapa aafin Sọun Ogbomọsọ ti le ni ọọdunrun ọdun. O ma n jẹ awọn nkan bii irẹsi, ẹwa, dodo, o si ma n mumi nigba kan laarin ọsẹ meji.
Bakan naa ni ijapa yii maa n ba Sọun sọ̀rọ̀ nigba to ba wu ninu ọdun kan.