You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Laa han mi, America Inauguration Joe: Wo àwọn eré orí ìtàgé tí Donald Trump ṣe kó tó fi ipò aàrẹ sílẹ̀
Ogunjọ oṣu kinni, ọdun igbejọba silẹ kii yẹ ninu iṣelu ijọba America lati ọdun pupọ seyin
Wo awọn ohun ti Donald Trump ṣe ṣaju idibo, lasiko idibo ati lẹyin idibo to yọ ọ kuro ni ipo aarẹ ilẹ America.
Mọ sii nipa " inauguration day' ilẹ America to maa n waye logunjọ, oṣu kinni ọdun iṣipo pada.
Wo awọn ileri ti Joe Biden ti ṣe fawon eniyan America ati erongba rẹ gbogbo lẹyin ibura ti yoo waye logunjọ oṣu yii.
Bakan naa ni o le wo bi ohun gbogbo yoo se ri bayii.