NGACMR: Ohùn tí àwọn alatilẹyin Super Eagles sọ lẹ́yìn tí Nàìjíríà borí Cameroon

Àkọlé fídíò, #NGACMR:Ohùn tí àwọn alatilẹyin Super Eagles sọ lẹyìn tí Nàìjíríà borí Cameroon

Awọn alatilẹyin ikọ Super Eagles Naijiria ti sọ nipa ireti wọn ninu idije Afcon lẹyin ti Naijiria bori ikọ Cameroon.

Akọroyin wa to jabọ lati ilu Alexandria sọ pe niṣe ni wọn ni awọn ko foya lati koju ẹnikẹni to ba kan ninu idije naa.

Ifẹsẹwọnsẹ to kan niwaju jẹ eleyi ti yoo pakasọ yala ti wọn ba koju Egypt tabi South Africa.