Bad teeth Model: Ojú máa ń tì mí láti rẹ́rìn ín nítorí irú eyín ẹnu mi ṣùgbọ́n mo dúpẹ́ mo padà dí arìnrìnoge- Omotola Ekundayo

Omotola Ekundayo gba BBC Yoruba lalejo nibi to ti sọrọ nipa irianjo aye rẹ.

O mẹnuba ohun to sọ ọ gi eleyin gatagata laye ati bi o ṣe n gbiyanju lati bori ironu ati idẹyẹsi awọn eeyan lori ayelujara.

Omotola sọ bo ṣe rirnirn ajo aye rẹ ko to di arinrinoge.

Wo arẹwa ti irẹwẹsi ọkan fẹ ṣe leṣe ko to bori rẹ pẹlu awọn ipenija rẹ.

Arinrinoge ti eyin rẹ ri bo ṣe ri yii ti di gbajugbaja arinrinoge.

O gba awọn to ni ipenija eya ara bii tirẹ ni imọran lati ma ro ara wọn pin.

Omotola Ekundayo ni eyin yii ti fun oun ni orukọ tuntun.