Kò ṣeé má gbọ̀ọ́
Ọrọ Sharia nilẹẹ Yoruba ti n ba ibo mi-in yọ o
Alaga CAN Ọyo, Ẹni ọwọ Joshu Akinyemiju, sọ fun BBC pe Sharia ki i ṣe ofin tijọba Oyo buwọlu
Ajọ Muric to n ja fun ẹsin Islam sọ ni tiẹ pe wọn n fi ẹtọ awọn ẹlẹsin Islam dun wọn ni.
Sultan Sokoto paapaa ni dandan Sharia nilẹ Yoruba.
Alaye wa ni BBC Yoruba
;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;
Ijọba apapọ ti fun ẹbi oloogbe Taiwo Akinkunmi to ṣe asia Naijiria ni miliọnu lọna ọgbọn naira
Ajọ National Orientation Agency lo fi sowedowe naa le ẹbi Akinkunmi lọwọ l'Ọjọbọ
Ọkan lara awọn ọmọ Oloogbe, sọ fun BBC pe awọn tiẹ ro pe ijọba ti gbagbe ileri rẹ ni.
,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,
Awọn aráàlú yìnbọn pa ọmọ ilẹ̀ Iraq tó dáná sun Kurani
Ọdun 2023 ni Momika to n gbe ni Sweden huwa yii niwaju mọṣalasi nla to wa ni Stockholm
Ọjọru ọsẹ yii ni wọn yinbọn pa a ti wọn si ju oku rẹ sinu ile kan lẹyin to ti n jẹjọ ni kootu
Ṣe ẹjọ ko ti ku s'Ake bayii?