Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́ - 4 Ọ́wàrà, 2024

Àkọlé fọ́nrán ohùn, Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́ - 4 Ọ́wàrà, 2024
Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́ - 4 Ọ́wàrà, 2024

Ile ẹjọ giga kan niluu Abuja ti paṣẹ fun gomina ipinlẹ Kogi tẹlẹ, Yahaya Bello, lati wa sọ tẹnu rẹ lori ẹsun ajẹbanu ti EFCC fi kan an

Ile ẹjọ naa ni Bello gbọdọ jọwọ ara rẹ fun EFC C lati gbe wa sile ẹjọ dipo ko fi ẹsẹ ara rẹ lọ ile ẹjọ ọhun

Lọ soju opo BBC Yoruba fun ẹkunrẹrẹ iroyin naa

Mi o mọ Bobrisky ri, a o pade ri, koda, a o tii bara sọrọ ri

Ajafẹtọ ọmọniyan, Femi Falana lo sọ bẹẹ ninu ifọrọwerọ kan

Falana ni lootọ ni Bobrisky pe ọmọ oun Falz pe oun nilo iranlọwọ owo lasiko to wa loọgba ẹwọn, amọ ko si idokoowo kankan laarin oun ati ẹlẹwọn ọhun

O kere tan, eeyan mejidinlọgọrin lo ti jade laye, ti ọpọ awọn mii tun dero ile iwosan

Lẹyin ti ọkọ oju omi kan dojude lorilẹede DR Condo

Kii ṣe igba akọkọ ree ti ọkọ oju omi yoo danu ni DR Congo

Latari bi awọn ọkọ oju omi ṣe maa n ko ero to pọ ju agbara wọn lọ