A ò ní ṣìrìn lọ́dùn tuntun -Imam ìjọ Shafaudeen in Islam, Sabit Olagoke gbàdúrà fáwọn ọmọ Nàìjíríà

A ò ní ṣìrìn lọ́dùn tuntun -Imam ìjọ Shafaudeen in Islam, Sabit Olagoke gbàdúrà fáwọn ọmọ Nàìjíríà

BBC Yoruba kan si Imam agba ninu ijọ Mosalasi Shafaudeen In Islam lati sadura ọdun awọn eeyan wa, papaajulọ fun gbogbo ololufẹ BBC Yoruba pẹlu ilana musulumi.

Imam Sabiat Olagoke ninu adura rẹ sọ pe ayọ lo ku lọdun yii.

Ati pe Allahurabi yoo fun ijọba Naijiria lọgbọn ati agbara lati ṣe ẹtọ to yẹ fun awọn ọmọ Naijiria.