Kò ṣeé má gbọ̀ọ́
Ẹni to sunmọ mi típẹ́-típẹ́, ti a jọ n sun abẹ orule kan naa lo ta mi soko ẹru ni Mali
Ah! Aye ma le o!
Adeola ọmọ Jumoke George, tọ jẹ oṣere tiata Yoruba lo sọ bẹẹ
Ẹṣi o!
O ni Malaysia loun ro pe oun n lọ tẹlẹ ki wọn to mori le Mali
Hmmmmm
Koda, o ni iṣẹ aṣẹwo ni wọn fẹ lọ fi oun ṣe lọhun ki oun to fariga
Ẹkunrẹrẹ wa loju opo BBC Yoruba
________________________________
Nipinlẹ Osun
Awọn olugbe Aduramigba niluu Ido Osun ti ṣalaye pe, ifẹhonuhan ti wọn ṣe lori ọna ti ijọba ṣe fun wọn ko lọwọ oṣelu ninu
Wọn sọ fun BBC pe
iṣẹ ajanbanku ni kọngila to gba iṣẹ títì naa ṣe fun awọn, koda agbara ojo gbe titi ọhun lọ lẹyin ọjọ kẹrin ti wọn da ọda si
_______________________________
O kera tan, eeyan mẹtadinlogji lo jade laye lẹyin ti adocoloro Israel balẹ si Gaza Strip
Awọn adoola ẹmi sọ pe inu ọkọ ofurufu ni ado oloro naa ti n jabọ to si n ṣọṣẹ lawọ ile ẹkọ, ile epo atawọn ibomii