Mi ò ní ẹ̀rí pé èmi ni mo bori ìbò ààrẹ lọ́dún 2023, ṣùgbọ́n mo mọ̀ pé èmi ni mo borí - Peter Obi
Mi ò ní ẹ̀rí pé èmi ni mo bori ìbò ààrẹ lọ́dún 2023, ṣùgbọ́n mo mọ̀ pé èmi ni mo borí - Peter Obi
Published
Oludije fun ẹgbẹ oṣelu NDC fun ipo aarẹ lọdun 2027, Peter Obi ti ṣalaye pe lootọ oun ko ni ẹri kankan to fidi rẹ mulẹ pe oun lo bori eto idibo sipo aarẹ lọdun 2027, sibẹ oun mọ pe oun loun bori.
Peter Obi sọ ọrọ yii lasiko to n ba BBC sọrọ ninu ifọrọwerọ kan.
Peter Obi ni 'kii ṣe gbogbo nnkan lo nilo ẹri tabi duro lori ẹri' amọ oun ṣi duro lori ọrọ oun pe oun lo bori ibo naa, kii ṣe Ààrẹ Tinubu.
Bi ẹ ko ba gbagbe, Peter Obi ni Oludije fun ẹgbẹ oṣelu Labour Party ninu idibo aarẹ lọdun 2023 ninu eyito ti ṣe ipo kẹta pẹlu ibo to le diẹ ni miliọnu mẹfa.



