Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Ile ẹjọ giga kan nilu Ibadan ti gba beeli Olori Ooni ana, Naomi Silekunọla ati Oriyomi Hamzat kuro ni ahamọ ọgba ẹwọn
Agbẹjọro Oriyomi, Adekunle Sobaloju, lo fidi ọrọ naa mulẹ fun BBC Yoruba nile ẹjọ ọhun laarọ oni ọjọ Aje
Amọ ile ẹjọ naa ṣekilọ pataki fun Oriyomi lori sisọ ohun ti oju rẹ lori ọrọ naa lori afẹfẹ
Ẹwẹ, bi igbẹjọ wọn ṣe n lọ nile ẹjọ giga naa ni wọn tun koju igbẹjọ nile ẹjọ majisreeti
Kaaaabiesi o! k'ade o pẹ lori, ki bata pẹ lẹsẹ, k'aṣẹ pẹlu lẹnu kanrinkese
Oriade wo lo n kan sara si?
Ṣe o fẹ sọ pe oo tii gbọ pe gomina ipinlẹ Oyo, Seyi Makinde ti gbe ọpa aṣẹ fun Alaafin tuntun, iyẹn
Akeem Abimbola Owoade
Awọn to wa sọ pe awọn ko faramọ iyansipo rẹ nkọ?
O n bi mi, ta ni ki n bi?
_________________________________________________________________________________
Nipinlẹ Eko
Ile igbimọ aṣofin ipinlẹ naa ti yọ adari ile ọhun, Mudashiru Obasa bii jiga
Igbesẹ ọhun ko ṣẹyin ẹsun aṣemaṣẹ ati aṣilo ipo ti wọn fi kan an
To ba fẹ mọ ẹkunrẹrẹ.....