Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Idunnu ti ṣubu l’ayọ fun awọn oṣiṣẹ ijọba Ipinlẹ Oyo bayii
Lẹyin ti ijọba ipinlẹ naa kede ẹgbẹrun lọna ọgọrin naira owo oṣu oṣiṣẹ to kere julọ
Kọmiṣọna eto iroyin, Dotun Oyelade lo fi ọrọ naa lede ninu atẹjade kan
Ẹgbẹ awọn oṣiṣe, NLC, ti wa kan sara si ijọba ipinlẹ ọhun fun igbesẹ naa
A fẹ́ kí Tinubu yọ̀nda okú Lagbaja fún wa kí á lè sin ín ní ìlànà ẹsin Mùsùlùmí nílùú rẹ̀
Olobu ti Ilobu, Ọba Ashiru Olatoye Olaniyan lo rawọ ẹbẹ bẹẹ si Aarẹ Naijiria, lẹyin iku ọga agba ileeṣẹ ologun, Taoreed Lagbaja
Kabiyesi Olobu sọ fun BBC pe, adanu nla ni iku ọgagun naa jẹ fun gbogbo ọmọ bibi Ilobu ati Naijiria lapapọ
Igbakeji Aarẹ Amẹrika, to tun du ipo Aarẹ, Kamala Harris ti sọ pe
Oun ti gba f’Ọlọhun, bẹ si ni oun ti juwọ silẹ fun Trump gẹgẹ bii ẹni ti araalu dibo fun lati di Aarẹ
Ogunjọ oṣu Kinni ọdun to n bọ ni iburawọle Trump gẹgẹ bii Aarẹ Amẹrika tuntun yoo waye