BBC dọ́gbọ́n fi fóònù ya àṣírí àti ìbẹ̀rù tó gbilẹ̀ ni Sudan, ìlú tó wà nínú ìdè ogun

Àkọlé fídíò, Idaamu ogun El Fasher, Sudan
    • Author, Heba Bitar
    • Role, BBC Eye Investigations
    • Reporting from, Darfur, Sudan
  • Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 5

"Ko fi ọrọ kankan siłę. O ti ku nigba ti wọn gbe lọ," Hafiza sọrọ jẹjẹ bi o ṣe n ṣalaye bi won ṣe ṣekupa iya rẹ ni ilu kan ni Darfue lasiko ogun abẹle ni Sudan to bẹrẹ ni odun meji sẹyin.

ẹni ọdun mọkanlelegun ranti bi ajalu ṣe ba idile rẹ bi iya rẹ ṣe jade laye, lori awọn ipe kan ti Ileeṣẹ BBC gbiyanju lati pe awọn eeyan to si ha sinu ogun naa ni el-Fasher.

Bi ọpọ Ogun ṣe n waye ni el-Fasher, o da bi pe wọn ti ja el-Flasher ti kuro ni awujo agbaye fun bi ọdun kan bayii, ti awọn akọroyin ko si Maye lati wọ ilu naa. Fun Cabo to peye, a n lo orukọ akọkọ awon beyan to fẹ ki a ya igbesi aye wọn , ti won si fe so iriri won lori fonnu fun BBC.

Hafiza ṣapejuwe bi o ṣe ṣadede bẹrẹ si ni ma gbe bukata aburo rẹ ọkunrin, ẹni ọdun Marun un ati obinrin meji.

Baba wọn ti ku lati bẹrẹ Ogun Abẹle

Sudan

Awọn alatako meji ni wọn ti fi igba kan jẹ ọrẹ- ti wọn si gba agbara papọ- ṣugbọn ọkọ gba arin wọn lori atilẹyin ajọ agbaye kan lati ijọba pada sọwọ ijọba awarawa.

Ile Haifa ni ilu kan to ku ti ileeṣẹ ologun n dari ni apa Ariwa Darfur, ni spa guusu orilẹese Sudan, ti wọn si ti bẹrẹ ogun pẹlu awọn agbebọn RSF fun bi oṣu mejila.

Ni oṣu kẹjo ọdun 2024, ado oloro kan bu gbamu ni ọja kan nibi ti iya ti lọ ta eroja ile.

''Ẹru le gan an. N ko le lọ sibi ti iya mi ti n ta ọja,'' Hafiza n sọ ninu fidio kan to ṣe lẹyin to gba fonnu lẹyin igba ti iya rẹ ku.

'' Mo lo gbogbo akoko mi ninu ile mi ti mo n fi sunkun.''

Awọn igun mejeeji ni wọn ti fẹsun kan pe wọn n mọmọ ṣekuọlu si awọn araalu, eyi ti wọn ni rara- RSF ti sọ saaju pe awon ko lọwọ ninu ẹsun ti orilẹede Amẹrika ati ajọ ajafẹtọ ọmọ niyan fikan wọn.

RSF lo n mujuto wiwọle ati jijade ilu naa, ti wọn si ma gba awon araalu laye lati jade, fun idi eyi, Hafiza gbiyanju lati mu awon aburo lati duro ti mọlebi ni agbegbe ti ko si ogun.

Sugbọn o duro lati sise lati le wa owo ṣe itọju wọn.

Ninu atẹjisẹ rẹ, o ṣapejuwe iriri rẹ lia si aṣo bora, omi fun awon akanda eda to n gbe ni awọn ile afọku, to si n pese iranlọwọ ni ile idana ilu, pese fun awọn to n aisan jẹjẹ ọkan, to n si gba owo diẹ fun iṣẹ to n ṣe.

Bakan naa lo n da sun.

"Mo ranti ibi ti iya mi ati aburo mi ma n duro si, inu mi bajẹ." o fikun.

Aworan Hafiza abi aburo rẹ

Oríṣun àwòrán, Hafiza

Mostafa

Oríṣun àwòrán, Mostafa

Ninu gbogbo fọnran ti Mostafa, ẹni ọdun mejilelọgbọn fi ransẹ si wa , oro ibọn jẹ ohun ti a n gbọ labẹ lẹ.

"Lọsan loru, ni a n gbọ arrow lati ọdọ RSF," o sọ.

Ni ọjọ kan, lẹyin to ṣe abẹwo si mọlẹbi, o ri ọkọ ayọkẹlẹ rẹ ti wọn ti fọ gbogbo ara rẹ ni Marin ilu .

"Gbogbo nnkan ti dojo dalẹ. Gbogbo ile ni wọn ti ja ," o sọ, to so da RSF lẹbi.

'Ko sibi ti alaafia wa ni el-Fasher. Ko si ẹni ti ọta ibọn o le ba, tabi oungbẹ ati ebi.

Ile Mostafa

Ninu atejisẹ mii, o sọrọ nipa ansi omi to mọ, ti ọpọ si n mu omi lati ile idọti kan.

Ati Mostafa ati ẹni ọdun mẹrindinlọgbọn Manahel, eni oun naa gba foonu BBC, ti out naa si n siṣẹ lọfẹẹ ni ile idana, ti awọn eeyan Sudan to n gbe ni ilu mii da jọ lati fi pese.

"Opọ awọn eeyan ni won ko lọ si ọja , ti wọn ba lọ, ọwọngogo gbode," Manahel ṣalaye.

"Gbogbo idile ti dọgba bayii- ko si olowo mọ ko si loose mọ.

Ounjẹ ti ươn je

Oríṣun àwòrán, Manahel

Lẹyin ti wọn ba sẹ irẹsi ati ọbẹ, wọn ma lọ gbe ounjẹ fun akanda ẹda to n wa ile. fun ọpọ wọn, ounjẹ ọkan ni wọn ma n jẹ lojumọ.

Nigba ti ogun bẹrẹ, Manahel sẹsẹ pari fast nibi to ti kọ imọ nipa Sharia ati Law.

Nigba ti ija de el-Fash, o kọ wọle pẹlu iya rẹ ati aburo rẹ mẹfa ti agbegbe ti alaafia wa.

"O padanu ile rẹ, gbogbo nnkan to ni, to si ni lati lọ wa ibi tuntun lati wa lia ni nkankan." o sọ.

Sugbọn baba kọ lati kuro ni ile wọn. Awon to wa ni agbegbe ni ohun ini wọn ti ko ma sọ, to si pinnu lati duro ti wọn.- Igbesẹ to fi pada padanu ẹmi rẹ.

O ni o ni wọn pada ṣekupa baba ni oṣu kẹsan an ọdun 2024 lati ọwọ RSF.

Ina dida

Oríṣun àwòrán, Manahel

Lati igba ti ogun naa ti bẹre, o le ni ẹgbẹrun meji eeyan to ti padanu ẹmi wọn tai farapa ni el-Fasher, gẹgẹ bi UN ṣe ṣalaye.

Ti ilẹ ba su, awọn ko ki n fi fẹ bẹ kuro ni ile wọn. Ai si ina ma jẹ ki ẹru ati jade ba ọpọlọpọ.

Koda awọn to n lọ ina Solar ma n bẹru lati ta ina mọnamọna ile wọn nitori ki ẹrọ drones ma ba le ri wọn. Manahel ṣalaye.

Asiko wa ti a ko nini anfani lati si oun ati awọn yooku fun ọpọ ọjọ. nitori wọn ko ri ayelujara.

Sugbọn pẹlu gbogbo rẻ, o ni nnkan to n ba Manahel ati Hafiza lẹru ti ilu naa ba bọ sọwọ RSF.

"Gẹgẹ bi obinrin, wọn le ba mi lopọ" Hafiza sọ ninu atẹjisẹ kan.

Aworan awọn ologun
Aworan Mostafa,

Oríṣun àwòrán, Mostafa

Lẹyin ọpọ riri, Hafiza, Mostafa ati Manahel ri pe igbesin aye el-Fasher ko ṣe gbe , to si jẹ pe nigba to di oṣu kọkanla ọdun 2024, awọn mẹtẹta ni lati kuro lọ si ilu mi to sumọ.

Nigba ti ile oloogun gba agbara ni olu ilu, Khartoum ninu oṣu ketą, Darfur si ni agbegbe ni awọn agbebọn n dari lọwọ.

"El-Fasher ti di ibi ibẹru," Manahel ni sọ bi o ṣe n ko ẹru rẹ

"A n lọ lai mọ ọjọ ọla ưa. N jẹ ma pada wa si el-Fasher? Nigba wo ni ogun yoo pari? A ko mọ nnkan ti yoo ṣẹlẹ."

Aworan ilẹ Sudan