Ǹjẹ́ o lè gba ọmọ tọ́? Kí làwọn ire àti ibi tó wà nínú gbígba ọmọ tọ́? Àwọn onímọ̀ ṣàlàyé
Ǹjẹ́ o lè gba ọmọ tọ́? Kí làwọn ire àti ibi tó wà nínú gbígba ọmọ tọ́? Àwọn onímọ̀ ṣàlàyé
Oro ṣiṣe agbatọ ọmọ jẹ eyi to ni ọpọ apade alude ninu nitori ire ati ewu to sodo si inu rẹ.
Amọṣa, pẹlu gbogbo eyi awọn eeyan kii ṣe alai sọrọ nipa rẹ lawujọ.
Fidio yii jẹ ọkan lara ohun to jade si oniruuru ijiroro lori iha ti kaluku kọ si ọrọ ṣiṣe agbatọ ọmọ, paapaajulọ fun awọn lọkọ-laya ti ko tii ri ọmọ bi.
Fidio yii ṣe agbeyẹwo awọn lọkọ-laya to ri ṣiṣe agbatọ ọmọ gẹgẹ bi ọna abayọ kan si airọmọbi wọn .
A gbe eyi kaleni ifẹgbẹkẹgbẹ pẹlu iha ti awọn miran lawujọ kọ sii, paapaajulọ awọn iya ati baba agba.





