FIFA women's world cup 2023: Àwọn ikọ̀ tí Naijiria yóò kojú àtàwọn nǹkan tó yẹ kí o mọ̀

Fifa women's world cup 2023

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Ikọ agbbọọlu obinrin Naijiria ti kede awọn ti yoo ṣoju rẹ ninu idije ife ẹyẹ agbaye awọn obinrin ti yoo bẹrẹ laipẹ.

Lara awọn ti yoo ṣoju Naijiria ti akọnimọọgba wọn, Randy Waldrum kede ni Asisat Oshoala, ati Rasheedat Ajibade.

Awọn orilẹ-ede mii ni Afririka ti yoo kopa ninu idije naa ni South Africa, Morocco ati Zambia.

Awọn ohun to yẹ ki o mọ nipa idije ife ẹyẹ agbeye awọn obinrin naa ree.

Nibo ni idije naa yoo ti waye ati pe igba wo ni?

Orilẹ-ede Australia ati New Zealand ni idije naa yoo ti waye.

Eyii ni igba akọkọ ti orilẹ-ede mejeji yoo pawọpọ lati ṣagbatẹru idije ọhun.

USA lo gba ife ẹyẹ idije naa kẹyin, wọn si ti ṣeleri lati tun gba ife ẹyẹ ọhun fun bayii, to ba ri bẹẹ yoo tumọ si pe wọn ti gba a nigba mẹta leralera.

Awọn orilẹ-ede to pegede lati kopa ninu ididje naa lọdun 2019 ti idije naa waye kẹyin jẹ mẹrinlelogun, amọ orilẹ-ede mejilelọgbọn ni yoo kopa ninu rẹ lọdun yii.

Awọn orilẹ-ede ti yoo kopa ninu idije ọhun lọdun yii ree

  • Australia
  • New Zealand
  • China (AFC)
  • Japan (AFC)
  • Philippines (AFC)
  • South Korea (AFC)
  • Vietnam (AFC)
  • Morocco (CAF)
  • Nigeria (CAF)
  • South Africa (CAF)
  • Zambia (CAF)
  • Canada (CONCACAF)
  • Costa Rica (CONCACAF)
  • Haiti (CONCACAF)
  • Jamaica (CONCACAF)
  • Panama (CONCACAF)
  • United States (CONCACAF)
  • Argentina (CONMEBOL)
  • Brazil (CONMEBOL)
  • Colombia (CONMEBOL)
  • Denmark (UEFA)
  • England (UEFA)
  • France (UEFA)
  • Germany (UEFA)
  • Italy (UEFA)
  • Netherlands (UEFA)
  • Norway (UEFA)
  • Portugal (UEFA)
  • Republic of Ireland (UEFA)
  • Spain (UEFA)
  • Sweden (UEFA)
  • Switzerland (UEFA)

Isọri awọn orilẹ-ede ti yoo kopa atawọn ti wọn yoo koju

Group A

  • New Zealand
  • Norway
  • Philippines
  • Switzerland

Group B

  • Australia
  • Republic of Ireland
  • Nigeria
  • Canada

Group C

  • Spain
  • Costa Rica
  • Zambia
  • Japan

Group D

  • England
  • Haiti
  • Denmark
  • China

Group E

  • USA
  • Vietnam
  • The Netherlands
  • Portugal

Group F

  • France
  • Jamaica
  • Brazil
  • Panama

Group G

  • Sweden
  • South Africa
  • Italy
  • Argentina

Group H

  • Germany
  • Morocco
  • Columbia
  • Korea Republic

Bi awọn ifẹsẹwọnsẹ yoo ṣe waye

Skip podcast promotion and continue reading
Èyí ni ìkànnì Whatsapp wa

Àjáàbalẹ̀ ìròyìn BBC News Yorùbá lórí WhatsApp rẹ

Darapọ̀ mọ́ wa nibì

End of podcast promotion

July 20

Group A: New Zealand vs Norway (8am)

Group B: Australia vs Republic of Ireland (11am)

July 21

Group B: Nigeria vs Canada (3.30am)

Group A: Philippines vs Switzlerland (6am)

Group C: Spain vs Costa Rica (8.30am)

July 22

Group E: USA vs Vietnam (2am)

Group C: Zambia vs Japan (8am)

Group D: England vs Haiti (10.30am)

Group D: Denmark vs China (1pm)

July 23

Group G: Sweden vs South Africa (6am)

Group E: Netherlands vs Portugal (8.30am)

Group F: France vs Jamaica (11am)

July 24

Group G: Italy vs Argentina (7am)

Group H: Germany vs Morocco (9.30am)

Group F: Brazil vs Panama (12pm)

July 25

Group H: Colombia vs South Korea (3am)

Group A: New Zealand vs Philippines (6.30am)

Group A: Switzerland vs Norway (9am)

July 26

Group C: Japan vs Costa Rica (6am)

Group C: Spain vs Zambia (8.30am)

Group B: Canada vs Republic of Ireland (1pm)

July 27

Group E: USA vs Netherlands (2am)

Group E: Portugal vs Vietnam (8.30am)

Group B: Australia vs Nigeria (11am)

July 28

Group G: Argentina vs South Africa (1am)

Group D: England vs Denmark (9.30am)

Group D: China vs Haiti (12pm)

July 29

Group G: Sweden vs Italy (8.30am)

Group F: France vs Brazil (11am)

Group F: Panama vs Jamaica (1.30pm)

July 30

Group H: South Korea vs Morocco (5.30am)

Group H: Germany vs Colombia (10.30am)

Group A: Norway vs Philippines (8am)

Group A: Switzerland vs New Zealand (8am)

July 31

Group C: Japan vs Spain (8am)

Group C: Costa Rica vs Zambia (8am)

Group B: Republic of Ireland vs Nigeria (11am)

Group B: Canada vs Australia (11am)

August 1

Group E: Vietnam vs Netherlands (8am)

Group E: Portugal vs USA (8am)

Group D: China vs England (12pm)

Group D: Haiti vs Denmark (12pm)

August 2

Group G: Argentina vs Sweden (8am)

Group G: South Africa vs Italy (8am)

Group F: Panama vs France (11am)

Group F: Jamaica vs Brazil (11am)

August 3

Group H: Morocco vs Colombia (11am)

Group H: South Korea vs Germany (11am)