Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́

Àkọlé fọ́nrán ohùn, Àkójọpọ̀ ìròyìn káàkiri Nàìjíríà
Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 1

Iya ati lilu to pọ lo jẹ ki n sa asala fun ẹmi mi

Ha ha, iwọ ati ta ni?

Ehn ẹmi kọ o, iyawo alaafin ana, Olori Dami lo kuku ṣalaye idi to fi ko ẹru rẹ lọsan gangan kuro nile Portable

Loootọ ma ni Portable gbe fidio kan jade nibi to ti n sọ awọn kobakungbe ọrọ si olori naa

Bẹẹ ni o, amọ Dami naa ti wa fe si sawọn ẹsun naa

Ki lo sọ ọ ati pe ki lo fa ija wọn gan?

Kan si oju opo bbc.com/yoruba fun ẹkunrẹrẹ

Eeyan to le ni ẹgbẹrun meji abọ lo foju ba ile ẹjọ lori iwa ajẹbanu laaarin oṣu mẹsan-an lọdun yii nikan

Ṣe bẹẹ naa ni iwa ibajẹ ṣe gbilẹ to ni Naijiria ni?

akojọpọ iroyin BBC yoruba lori awọn ẹsun manigbagbe ati igbẹjọ to waye lori iwa jẹgudujẹra Naijiria lọdun 2024 leyi ti jẹyọ

Ibanujẹ gbọkan awọn eeyan ilu Rift Valley ni Kenya

Latari bawọn dokita kekeke ṣe n para wọn lorilẹ ede naa nitori aigbowo oṣu

Ti wọn si n ṣiṣẹ fun ọpọ wakati lai sinmi

Fun ẹkunrẹrẹ awọn iroyin yii

Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́