Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Ileeṣẹ ifọpo Dangote ti sọrọ lori awuyewuye to n waye lori iye ti wọn n ta epo bẹntiro ni Naijiria
Dangote ni ₦990 lawọn n ta epo fun awọn tanka, nigba ti wọn n ta a ni ₦960 fun ọkọ oju omi
Ọrọ yii lo jẹyọ lẹyin ti ẹgbẹ awọn alagabta epo sọ pe
Epo Dangote ti wọn n po ni Naijiria wọn ju eyii ti wọn n ko wọle lati oke okun lọ
Laye faabada! Mi o jẹ tapa si awọn oniṣẹṣe, nitori emi gan ti gbeegun ri
Olorin ẹmi, to tunjẹ sọrọsọrọ ori redio, Yinka Ayefele lo sọ bẹẹ
Lẹyin ti awọn oniṣẹ ṣewọde lọ ọọfisi rẹ lẹyin ifọrọwerọ kan to ṣe nibi ti ọkunri kan ti sọ pe oun maa n fi odidi eeyan bọ oriṣa
Lawọn oniṣẹṣe ba yari awọn kii fi eeyan ṣe irubọ
Nilẹ Amẹrika
Gbogbo eto lo ti to fun idibo Aarẹ ti yoo waye lọla ode yii
Aarẹ tẹlẹ, Donald Trump ati obinrin bii ọkunrin, Kamala Harris ni yoo maa forigbari
Fun gbogbo bi eto idibo naa yoo ṣe lọ...