Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Abi o ri ohun ti mo ri?
Ki ni nnkan naa?
Ijọba Naijiria ti fẹ gbe owo beba ẹgbẹrun marun-un naira ati ẹgbẹrun mẹwaa jade ati pe ọjọ Kiini oṣu Karun-un ni a o bẹrẹ si maa na
Irọ nla, ile ifowopamọ agba Naijiria, CBN ni iroyin ofege ni iroyin naa pe ko si igbesẹ to jọ bẹẹ
xxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxx
Mi o mọ pe maa wa laye, ori lo ko mi yọ
Ọkan lara awọn ọdẹ to moribọ lọwọ iku nibi iṣẹlẹ iṣekupani ni Uromi lọ bẹẹ fun BBC
Abubakar Shehu to ṣalaye bi iṣẹlé naa ṣe waye sọ pe
Ile akọku kan ni oun sa si bi wọn ṣe n dana sun awọn akẹgbẹ oun
xxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxx
Mo ma tun ri tuntun
Ki tun ni?
Ọkunrin kan ree to n ra omi ọmu mu lori ayelujara
Lẹyin ti ipinya waye laaarin ohun ati iyawo rẹ to maa n mu omi ọmu rẹ tẹlẹ
Jameson Ritenour ni lati igba toun ti n mu omi ọmu ni iṣan ara ti n jade si, toun si lokun ati agbara
Ṣawọn onimọ sayẹnsi wa fidi eyi mulẹ?
Fun ẹkunrẹrẹ














