You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
A ò ní juwọ silẹ fun idunkoko latọdọ Amẹrika
Lati gba awọn ọmọ orilẹede Venezuela ti wọn fẹ le kuro ni Amẹrika wa si Naijiria
Minisita fọrọ ilẹ okeere Naijiria, Yusuf Tuggar ṣalaye pe
Awọn idojukọ to n koju Naijiria lọwọ yii
Ko le jẹ ki wọn gba awọn ẹlẹwọn lati orilẹ èdè mii
xxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxx
Ajọ to n gbogun ti iwa ajẹbanu ni Naijiria, EFCC
Ti ke gbajare pawọn oloṣelu kan ti n kowo ti wọn fi ọna eburu ko jọ sinu apo owo crypto
Lojuna ati ma le fun awọn gbofinro ni anfani lati ṣewadii wọn
Ọga agba EFCC Ola Olukoyede sọ pe bii crypto ṣe jẹ ayipada si sisan owo lọja agbaye
Lo tun jẹ ọna fun awọn kọlọrọsi ẹda kan lati ko owo ilu pamọ
xxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxx
Gbogbo ibudo idibo ti wọn ti ba ji apoti ibo gbe ni atundi ibo ti maa waye nibẹ
Alaga ajọ to n ri si eto idibo ni ipinlẹ Eko, Bola Okikiolu-Ighile lo sọ bẹẹ lori eto idio ijọba ibilẹ ti yoo waye lọla
O sọ pe gbogbo eto lo ti wa ni sẹpẹ lati ri daju pe eto idibo naa lọ ni irọwọrọsẹ