Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́

Àkọlé fọ́nrán ohùn, Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́ lórí BBC Yoruba
Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́

Eyi ni akojọpọ awọn ohun to n ṣẹlẹ to tayọ kaakiri agbaye.

Lọsẹ yii, ohun tá agbẹ̀wò ni ni bí àwọn gómìnà ẹkùn ìwọ̀ oòrùn Nàìjíríà, ìyẹn ìpínlẹ̀ Eko, Ogun, Osun, Ogun, Oyo àti Ekiti ṣe ti panupọ̀ láti máa kọrin ìbílẹ̀ kan ṣoṣo.

A ṣe àkọ́ọ́lẹ̀ orin náà àti bí wọ́n ṣe ń kọ ọ́ sí ojú òpó wa.

Kọ́ nípa orin ìbílẹ̀ náà níbí yìí.

Ọmọ Yoruba rere to mọ aṣa ni mi

Ohun lo jẹ ki n fi iṣubu ki awọn alalẹ lori ayajọ ijọba awaarawa ni Naijiria

Aarẹ Bola Tinubu lo ṣalaye ọrọ lẹyin ti fidio bo ṣe ṣubu nigba to fẹ wọkọ nibi ayajọ ijọba awaarawa to waye lọjọru ṣe gba ori ayelujara

Ṣaaju ni ileeṣẹ aarẹ ni digbi ni Tinubu wa pe ko si ohunkohun to ṣe e lẹyin to ṣubu naa.