Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́ - 2 Ọ́wàrà, 2024

Àkọlé fọ́nrán ohùn, Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́ - 2 Ọ́wàrà, 2024
Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́ - 2 Ọ́wàrà, 2024

Gbogbo ẹyin ti ti ẹ fẹ ṣe atunṣe si orukọ tabi ọjọ ibi NIN, eti yin melo?

Maa wi wọn n gbọ

Ajọ to n ri si iforukọsilẹ araalu ni Naijiria, NIMC kede pe araalu ko nilo lati yọju si ọọfisia wọn mọ lati ṣe awọn atunṣe kan

Ṣe lootọ?

Wọn araalu le maa lọ soju opo tuntun ti wọn ṣẹṣẹ ṣi bayii lati maa ṣe awọn atunṣe naa funra wọn lai yọju si ọọfisi NIMC

O kere tan, ọgọrun eeyan ti di awati nipinlẹ Niger lẹyin ti ọkọ oju omi kan dojude nibẹ

Iroyin ni wọn ti ri oku ọgọta eeyan yọ ninu odo lẹyin iṣẹlẹ ọhun

A gbọ pe ero bii ọọdunrun lo wa ninu ọkọ oju omi naa, eyi to gbera lati ileto kan ti wọn n pe ni Mundi.

Pupọ ninu awọn ero ọkọ naa lo jẹ ọmọde ati obinrn