Àrá mé rírí, ìyá ẹni ọdún 115 gbé igbá óròkè nínú ìdíje èré sísá.
Àrá mé rírí, ìyá ẹni ọdún 115 gbé igbá óròkè nínú ìdíje èré sísá.
Ipinlẹ Haryana lorilẹede India gba alejo ohun tuntun to ya ọpọ lẹnu nigba ti iya arugbo kan, ẹni ọdun marundinlaadọfa gbe igba oroke nibi idije ere sisa.
Rambi bẹrẹ ere sisa ni ọdun 2021, to si ti fi itan lelẹ lorilẹede naa.
Ọmọ-ọmọ, Sharmila to ba awọn akọroyin sọrọ sọ pe iya arugbo naa ni iṣoro diẹ pẹlu ọrọ gbigbọ.
Nigba to n ba iya naa sọrọ pe bawo lo se ri lara rẹ lẹyin to gba ami ẹyẹ goolu.
Iya naa fọhun pe inu oun dun pupọ
Rambi gba ami ẹyẹ nibu ere sisa 100m ni iṣẹju 45.50 ni ẹni ọdun marundinlaadọfa.
Sharmila ṣalaye, “Rambi gba goolu akọkọ lẹyin to pari ere 200m ni iṣẹju aya mẹrinleladọrin
“Ago mẹrin idaji ni Rambi ma n ji, to si ma jafafa ni gbogbo igba.
“O ma n se ere idaraya ni gbogbo igba




