Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́

Àkọlé fọ́nrán ohùn, Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́

Ile ẹjọ ti gba beeli Amofin Dele Farotimi to n jẹjọ ibanilorukọjẹ ti Aarẹ Afẹ Babalola pe e

Nibi igbẹjọ rẹ to waye niluu Ado-Ekiti ni adajọ ti kede bẹẹ lọjọ Ẹti

Miliọnu lọna ọgbọn naira, oniduro meji atawọn nnkan mii ni Onidajọ̀ Abayomi Adeosun la kalẹ fun beeli naa.

Jẹ n gbọ wọn nao

Kan si bbc.com/yoruba

>>>>>>>>>>>>>>>>>>>>>>>>>>>>>>>>>>>>>>>>>>>>>>>>>>>>>>>>>>>>>>>>>>>>>>>>

Ààfin Ooni Ile-Ife ti sọ̀rọ̀ lórí àpèjẹ Olori ana, Naomi tí ọ̀pọ̀ ọmọdé ti kú n'Ibadan

Eeyah, ki ni Kabiyesi wi nipa olori tẹlẹ naa?

Wọn ni awọn ba Naomi Ogunseyi daro ohun to ṣẹlẹ

Ati ki tun ni?

Ile Oduduwa tun ṣeleri lati ṣe iranwọ lori akitiyan lati titu awọn obi to padanu ọmọ wọn ninu iṣẹlẹ

Tẹsiwaju

Lọọ ka eyi to ku loju opo wa

Irọkẹkẹ lati yan Ọwa Obokun ilẹ Ijesa tuntun gbọdọ dawọ duro na

Ki lo de?

Ọmọba mọkanla pe ẹjọ tako Gomina Adeleke, wọn lo fẹẹ fi ẹni ti wn ko yan jọba

Adajọ Aderibigbe ti paṣẹ idaduro bayii fun gomina atawọn afọbajẹ

Ki ni yoo wa ṣẹlẹ ?

Kan si BBC. Com/ Yoruba

Aworan Ko see ma gbo o