Kí ni ìtumọ̀ ilẹ̀ yíyọ̀ àti ohun tó máa ń fa ìṣẹ̀lẹ̀ náà èyí tó ń mú ẹ̀mí ọ̀pọ̀ èèyàn lọ?

Oríṣun àwòrán, EPA-EFE/REX/Shutterstock
- Author, Luis Barrucho
- Role, BBC World Service
- Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 4
Ilẹ yiyọ lo ma n fa ọpọ ajalu ju eyikeyi iṣẹlẹ ilẹ-aye mii ati pe o le waye nibikibi ni agbaye, gẹgẹ bii WHO se ṣalaye.
Awọn amoye fihan pe iṣẹlẹ yii n waye ni loorekoore nitori iyipada oju-ọjọ, pẹlu ireti lati tun tẹsiwaju.
O ti waye ni Indonesia, Nepal, ati Papua New Guinea lọdun yii, nibi ti ọpọ padanu ẹmi wọn, dukia wọn, ti awọn si farapa.
Nibi, a ṣawari awọn ohun ti o fa ilẹ riri, oriṣiriṣi iṣẹlẹ riri, ati bi o ṣe le daabobo ararẹ ati awọn to yi rẹ ka lasiko naa.

Oríṣun àwòrán, Reuters
Ki ni ile riri?
Ilẹ-riri jẹ didawo apa apata ati ilẹ. Iṣẹlẹ yii le waye lojiji, tabi diẹdiẹ fun igba pipẹ
Wọn ma n waye nigba ti ipa wọn ba ju ti eyi to n fa silẹ tabi ju eyi to n mu wọn duro, gẹgẹ bii British Geological Survey ṣe sọ.
Ki ni awọn ohun to ma n fa ile riri?
Ọpọ nnkan lo ma n fa iṣẹlẹ ilẹ riri.
Gẹgẹ bi US Geological Survey (USGS) se ti ṣalaye, "llẹ riri le waye nitori ojo arọda, iyin, ati ayipada omi, ẹkun omi ati awọn nnkan mii.
Ilẹ riri tun ma n waye ni abẹ omi. Atẹgun nla le fa eyi, to si le fa sunami ti yoo ba gbogbo agbegbe jẹ.
Ajọ WHO ni awọn agbegbe ti iṣẹlẹ ilẹ riri le ti waye ni:
- Agbegbe oke nla tabi ibi ti apata pọ
- Ilẹ ti ina ti jo
- Agbegbe ti awọn eeyan sisẹ lori wọpn boya sisun oko
- Agbegbe ti omi n gba kọja
- Agbegbe ti ọpọ ọmi wa

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Bawo o se moribọ lọwọ ilẹ riri?

Oríṣun àwòrán, Getty Images
Ilẹ-riri ti fa ajalu si apapọ eeyan to jẹ milọnu 4.8 ati pe o fa iku ojiji fun eeyan to le ẹgbẹrun mejidinlogun laarin ọdun 1998 si 2017, gẹgẹ bii WHO ṣe sọ.
Ajọ Red Cross ti Ilu Amẹrika gbanimọran pe ki eeyan suure kuro lẹsẹkẹsẹ ni agbegbe ti iṣẹlẹ naa ba ti waye, ko si jẹ ki awọn eeyan to wa ni ayika ati awọn alaṣẹ mọ nipa iṣẹlẹ naa ni kiakia.
O tun rọ awọn eeyan lati ma tẹti si awọn ohun, bi ki igi ma pariwo. Fun awọn to n gbe ni ẹgbẹ omi, o gba ni wọn imọran lati ma wo bi ẹkun omi si n pọ si tabi dinku si tabi omi naa se n mọ tabi dọti si

Awọn imọran to fi le dabobo ararẹ
Iwadi kan ti fasiti ti Washington ni Amẹrika ṣe lati mọ ọna ti eeyan fi le dabobo ararẹ. Awọn oniwadi ṣa wọn jọ ti wọn si ṣe itupalẹ awọn igbasilẹ mejidinlogoji nibi ti iṣẹlẹ ilẹ riri ti se akoba fun awọn ile ti awọn eeyan n gbe.
“Awọn igbesẹ kan ti ko nira tabi wọn wa ti eeyan le gbe lati dabobo ara rẹ lasiko ilẹ riri,” Joseph Wartman, ọjọgbọn lati ẹka imọ ẹrọ ṣalaye.
O ni igbesẹ kiakia ti eeyan le gbe ni ko suure duro si ilẹ ọke wa,ti irufẹ eeyan ni idaju wa pe yoo ye.
Awọn imọran mii, sisi ilẹkun ati ferese , ki eeyan si ma pariwo to jẹ pe ilẹ ti bo eeyan mọlẹ.
Bawo ni iṣẹlẹ iriri se buru to?
"Diẹ ninu awọn ilẹ-riri le yara ju bi eeyan se le sare lọ, to si le fa waye ni airo tẹlẹ, o le wa fun ọpọ ọjọ, ọsẹ tyabi ju bẹẹ lọ,”," USGS sọ.
Gẹgẹ bi WHO ṣe salaye, iṣẹlẹ ilẹ-riri le ja si ọpọ iku ati ifarapa lati inu omi ti n ṣan.
Ohun pato to ma n fa iku ni ibanujẹlokan tab airi aye lati mi labẹ ilẹ.
Ṣugbọn ohun to ba waye lẹyin iṣẹlẹ lewu. WHO sọ pe, “Ilẹ-riri tun le se akoba nla si eto ilera ati awọn ohun to ṣe pataki, bi omi, ina tabi awọn ẹrọ ibaraẹnisọrọ.”
Ina le gbe awọn eeyan, ba omi jẹ, afẹfẹ gaasi le ja to si le ifarapa tabi aisan.
Se ilẹ riri ni ajọsepọ pẹlu ayipada oju ọjọ?

Oríṣun àwòrán, Getty Images
Awọn amoye sọ pe iyipada oju-ọjọ ati awọn oorun ọjọ le fa iṣẹlẹ ilẹ riri
USGR sọ “Ile riri ni o ma n waye ni awọn agbegbe kan nitori ayipada oju ọjọ, bi ki ojo ma rọ
Gẹgẹ bi WHO se sọ, eyi le waye ni awọn agbegbe ti oke pọju si pẹlu iyin












