Kò ṣe á má gbọ̀ ọ́

Àkọlé fọ́nrán ohùn, Àkójọpọ̀ ìròyìn káàkiri Nàìjíríà
Kò ṣe á má gbọ̀ ọ́

Ẹyin oṣiṣẹ, ẹ mura fun iyanṣẹlodi alaini gbedeke

Ọjọ wo lo di agbẹnusọ awọn oṣiṣẹ?

Ẹgbẹ oṣiṣẹ Naijiria, NLC lo ma n sọ fawọn ọmọ ẹgbẹ wọn lawọn ipinlẹ to ṣi n lọra lati san ilana owo oṣu tuntun alaadọrin ẹgbẹrun naira lati gbaradi

Ṣe pe ipinlẹ kan wa ti gomina ko i tii buwọlu owo yii?

NLC ni ipari oṣu yii ni gbedeke fawọn gomina ipinlẹ tọrọ kan

Jẹ ki n tete lọ soju opo bbc.com/yoruba lati mọ boya ipinlẹ mi wa lara wọn

Ihin ile ọhun ile

Lo difa fawọn ọmọ Naijiria mẹrin yii

Ti wọn dibo yan sipo oṣelu lorilẹede Amẹrika ati Australia

koda ọmọ Yoruba ni mẹta ninu wọn

Fauzia/Akinlabi, emi gan n wo orilẹede ti mo ti le lọ gbapoti o

ṣe o ti gbe tilẹ yi tan ni?

ẹwọn gbere ni mo fẹ fawọn afurasi ọlọpaa to ṣekupa ọmọ kan ṣoṣo ti mo bi o

Iya Sulyman Ayeyemi, akẹkọọ poly to kagbako iku lọwọ awọn ọlọpaa kan ni ipinlẹ kwara lo sọ bẹẹ

Alaye iroyin yii n bẹ loju opo bbc.com/Yoruba.

Kò ṣe á má gbọ̀ ọ́