Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Akọtun iroyin Ko ṣe e ma gbọ ọ ti ọsẹ yii tun balẹ gẹgẹ bi ìse wa.
Omi tuntun to ru ti ẹja nla si sọ ninu rẹ ni ilu Ibadan, olu ilu ipinlẹ Oyo wa lara awọn iroyin ta a mu tọ yin wa lọtẹ yii.
Ni ọjọru ni gomina Seyi Makinde ṣi aafin tuntun lẹyin ọgbọn ọdun ti ni aafin to jẹ ti ilu gbẹyin.
Bakan naa la mu iroyin nipa bi ile ẹjọ to ga julọ ni Naijiria ṣe ti pa a laṣẹ fawọn gomina lati yọwọ kuro ninu kiko oeo awọn ijọba ibilẹ si aṣuwọn owo wọn mọ.
Ẹ tẹti si fọnran to wa loke yii lati gbọ ẹkunrẹrẹ awọn iroyin naa.