You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
"Ẹní bá rokúròyín, mo wíi lórúkọ Olúwa, ọ́sán gangan làá gbọ̀'kú aró, òjijì làfọ̀n wọ̀ …"– Àgbà òṣèré tíátà, Lere Paimo wúre ọdún
"Ẹní bá rokúròyín, mo wíi lórúkọ Olúwa, ọ́sán gangan làá gbọ̀'kú aró, òjijì làfọ̀n wọ̀ …"– Àgbà òṣèré tíátà, Lere Paimo wúre ọdún
Alagba Lere Paimọ ti ọpọ mọ si Ẹda Onileọla ti fi ohun adura ranṣẹ si gbogbo ọmọ kootu-o-jiire jakejado agbaye fun ọdun tuntun to wọle de.
ninu adura rẹ, Baba Ẹda, gẹgẹbi ọpọ ṣe maa n pe wọn ke pe eledumare fun abo ati ipamọ gbogbo mutumuwa. bakannaa ni Baba tun ke si Eledumare ko maṣe jẹ ki oju ti koowa.
"Nínú ọdún tuntun yìí, ojú yín ò ní rí ibi, ire lẹ óò máa rí".