Kò ṣe é má gbọ̀ọ́
Laaarọ kutu ọjọ Aje oni, ẹlẹwọn mejla sa lọ lọgba ẹwọn Koton Karfe, ipinlẹ Kogi.
Haa, bawo lo ṣe ṣẹlẹ?
Agbẹnusọ ọgba ẹwọn naa, Abubakar Umar, ṣalaye pe awọn ẹlẹwọn to n reti igbẹjọ lo sa jade lẹwọn
O ṣalaye pe awọn ti ri meji mu pada ninu wọn.
Ṣugbọn oṣiṣẹ ọgba ẹwọn kan di oloogbe ṣa o.
Ka ẹkunrere loju opo wa.
,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,
Ile ẹjọ South Korea kan ti da Olootu ijọba ti wọn yọ nipo, Han Duck-soo pada.
Oni ọjọ Aje ni kootu paṣẹ pe ki Han pada sipo aarẹ gẹgẹ bii adele.
Oṣu Kejila ọdun to 2024 ni wọn yan an sipo lẹyin ti aarẹ tẹlẹ, Yoon Suk, ṣe ofin lile.
Ṣugbọn ọsẹ keji ti wọn yan adele tuntun yii ni awọn aṣofin dibo yọ ọ nipo
Ki lo kan lẹyin aṣẹ kootu bayii
,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,
Oni ọjọ kẹrinlelogun, oṣu Kẹta ni ayajọ ikọọfẹ lagbaaye.
O yẹ ki o mọ nipa oriṣi ikọọfe to wa
Bo ṣe n tan kalẹ, apẹẹrẹ ti eeyan yoo maa ri
Njẹ ikọọfẹ tiẹ gboogun bi?
Ajọ ilera lagbaye, gba awọn eeyan nimọran lati gba abẹrẹ ajẹsara BCG fun ọmọ ikoko
Ati ki tun ni
