Kò ṣeé má gbọ̀ọ́

Àkọlé fọ́nrán ohùn, Kò ṣee má gbọ̀ọ́ kaakiri agbaye
Kò ṣeé má gbọ̀ọ́

Àwọn ológun wà níbí lóòótọ́, ṣùgbọ́n kò sí ààbò fún wa"

Awọn eeyan ti Boko Haram le nile ni Borno lo sọ bẹẹ

BBC ṣatupalẹ bi ikọ naa ṣe ti fi kun ikọlu ati idaamu awọn eeyan leralera lapa Ariwa Ila-Oorun Naijiria.

Akọsilẹ UNDP sọ pe o le ni eeyan ẹgbẹrun marundinlogoji ( 35,000) ti Boko Haram ti pa laaarin 2009 si 2024.

,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,

Dakun, ṣe lootọ ni Taiwo Awoniyi wọ coma

Bẹẹ ni, agbabọọlu ọmọ Naijiria naa wa lẹsẹ kan aye-ẹsẹ kan ọrun lẹyin iṣe abẹ akọkọ.

Ọjọ Aiku ni Awoniyi kọlu opo ojule lasiko ifẹsẹwọnsẹ Nottingham Forest ati ẹgbẹ Leicester.

BBC gbọ pe ifun Awoniyi bẹ lasiko to kọlu opo ojule naa

Bawo wa ni bayii?

,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,

Ojú ọ̀nà Akure sí Ọgbagi di pàkúté ikú, ẹmí arìnrìnàjò ń bọ́ púpọ̀ torí ìjàmbá ọkọ̀, ìkọlù adigunjalè àtàwọn ajínigbé"

Ọpọ eeyan lo tun n padanu ẹmi loju ọna ijọba apapọ yii latari koto giriwo.

BBC Yoruba de ojú ona náà, fun ẹkunrẹrẹ