Coronavirus: Mọ ọ̀nà láti tóju fóònu rẹ kí o ma ba ko àrùn
O ṣe pàtàkì ki a ma mó ṣe imótótó fóònu ìléwọ bi aṣe n ṣe itọjú ọwọ ni ìgbà gbogbo.
Ní ọ̀pọ̀ ìgbà, ọ̀pọ̀ ló n kọ ibi ara si fífi ọṣẹ fọ̀wọ́ lai mọ pe lẹyin ọṣẹ náà, o ṣeeṣe ki kòkòrò àifojuri náà tún pada si ọwọ ẹni ti ìmọtoto tó yẹ ko ba si fun fóònù.
Àwọn ọnà ti ènìyàn lé gbà láti ṣe àmojuto foóǹu lo wà nínú fọ́nran òkè yìí.