Olumide Aderinokun: Ẹ̀jẹ̀ Obasanjo sì wà ní PDP, gbágbá ló wà lẹ́yìn mi
Olumide Aderinoku tíí ṣe olùdíje sílé aṣòfin àgbà fẹ́gbẹ́ PDP ní Ogun Central bá BBC Yorùbá sọ̀rọ̀ lórí àfojúnsùn rẹ̀ fún aráàlú, tí wọn bá dìbò fun.
Olumide Aderinoku tíí ṣe olùdíje sílé aṣòfin àgbà fẹ́gbẹ́ PDP ní Ogun Central ti bá BBC Yorùbá sọ̀rọ̀ lórí àfojúnsùn rẹ̀ fún aráàlú, tí wọn bá dìbò fun.
Gẹgẹ bi oludije naa se wi, ilu ti le pupọ ju laye isejọba APC, ti oun ko si nigbagbọ pe gbogbo eroja le wn to bayii.
"Lójú ayé mi, n kò gbàgbọ́ pé a le ra búrẹ́dì ní N800 àbí N1000"
- PDP àti APC kọlu ara wọn l‘Eko àti Osun, ọ̀pọ̀ èèyàn fara pa
- Bí ìbò 2023 ṣe ṣúnmọ́lé, wo ohun tó yeͅ kó o mòͅ nípa rẹ̀
- Tinubu tún pàdé ìyá arúgbó Kwara tó ń ṣàdúrà fun nínú fídíò kan, ọ̀rọ́ bọ́
- Àwọn òṣìṣẹ́ ọba, aráàlú ń tara bí wọn kò ṣe rí káàdì ìdìbò wọn gbà
- Ìgbéyàwó mi ti túká àmọ́ irọ́ ni pé mo lu ìyá ọkọ mi – Wunmi Toriola
Aderinoku ni birikila ni oun, ti oun si n ba awọn onisẹ ọwọ miran sisẹ papọ eyi to mu ki oun sun mawọn eeyan to wa ni ẹsẹ kuku lati mọ ibi ti bata ti n ta wọn lẹsẹ́.
Oludije sipo asofin agba naa wa sọrọ nipa ajọsepọ rẹ pẹlu aarẹ tẹlẹ ni Naijiria, Oluseguun Obasanjọ, Ibikunle Amosun ati idi to se n dije naa.
Bakan naa lo tun foju tẹmbẹlu isejọba gomina APC ni Ogun, Dapo Abiodun eyi to ni o mẹhẹ pupọ.
- Ẹgbẹ̀ òṣèlú PDP wọ́ Tinubu lọ sílè ẹjọ́, rọ ilé-ẹjọ́ láti wọ́gilé tíkẹ́ẹ̀tì rẹ̀
- Àwọn òṣìṣẹ́ ọba, aráàlú ń tara bí wọn kò ṣe rí káàdì ìdìbò wọn gbà
- Oorun Tinubu ti pọjù, kò dá pé lára àti ní ọpọlọ - Adarí ìpolongo Tinubu tó fipò sílẹ̀
- Gbogbo ọkàn mi ni mo fi sin Naijiria, n kò já ẹnikẹ́ni kulẹ̀ – Buhari
- Mama Rainbow ṣèdárò ọkọ rẹ̀ lẹ́yìn ọdún 39 tó jáde láyé