You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Oba Gbolahan Timson Shomolu: Obasanjo ti jẹ́wọ́ pé 'Mistake' ni Buhari ṣùgbọ́n...
Tinubu náà a ti mọ̀ pé òun ṣe àṣìṣe ni Buhari ṣùgbọ́n ẹnu ẹ kò gbàá mọ́- Oba Shomolu Bariga,
Oba Gbolahan Timson to jẹ Jagunmolu ti ilu Shomolu Bariga ni ipinlẹ Eko gbalejo BBC Yoruba.
Kabiesi sọrọ nipa oṣelu Naijiria.
O mẹnuba aṣiṣe ti awọn bii Tinubu Ahmed to jẹ eekan ninu iṣelu iran yoruba ṣe se asise lati gbaruku ti Aarẹ Buhari lati de ipo adari Naijiria laisko yii.
- Njẹ́ o mọ̀ pé bíi ọdún 700 sẹ́yìn ni wọ́n ti ń bọ Osun-Osogbo? Mọ̀ síi nípa ìtàn ojúbọ̀ nàá
- Ìjọba Amẹ́ríkà ti kó abẹ́rẹ́ àjẹsára Covid-19 mílíọ̀nù mẹ́rin fún Nàìjíríà
- Ẹ fún wa ní oṣù márùn ún láti fí lé àwọn ajínigbé Fulani kúrò nínú igbó- Olórí Fulani
- Irọ́ ní ò, Adeyinka Daniel, akẹ́kọ̀ọ́ FUTA tí kú kí wọ́n tó gbé e wá sí ''health Centre'' FUTA
- Àlááfíà ni Bola Tinubu wà - Sanwo - Olu
- Olórí ọ̀dọ́ ẹgbẹ́ PDP sọ àbùkù ọ̀rọ̀ sí Ààrẹ Buhari àti SGF, ẹ̀wọ̀n jàntò ló rí he!
Lori Ẹgbe Okunkun?
Oba Gbolahan sọrọ lori iṣẹlẹ ẹgbẹ okunkun to n peleke lojoojumọ ni ẹgbẹ okunkun n peleke sii laisko kan ni agbegbe oun.
O sọ bi 'Pyrate'ṣe bẹrẹ pẹlu Wole Soyinka ni Fasiti Ibadan gẹgẹ bii ọna lati fi kọ iya ti awọn Olukọ fi n jẹ akẹkọọ ati awọn ololufẹ wọn ni.
O ni nigba to ya, Oun ati awọn Baalẹ oun ati awọn eeyan Shomolu Bariga lo jọ tọwọ bọ iwe adehun pe ki wọn pa ọmọkọmọ ti wọn ba ba ibọn lọwọ rẹ.
O ni lẹyin pipa pẹlu agbara ofin yii ni nkan n rọju diẹ pada.