US Vice President: Ẹ wo ìtàn obìnrin àkọ́kọ́ tí yóò jẹ igbákejì Ààrẹ ilẹ́ Amẹrika!

Sẹnetọ Kamala Harris ti ni bio tilẹ jẹpe oun ni obinrin akọkọ ti yoo dipo igbakeji aarẹ mu lorilẹede Amẹrika, oun gbagbọ wi pe ọpọlọpọ eniyasn ni yoo jẹ lẹyin oun.

Kamala Harris ni awọn arinrinajo wa si orilẹ-ede Amerika lati orilẹede India ati Jamica.

Ki o to di igbakeji aarẹ, oun ni olootu eto idajọ ni ipinlẹ California.

Ẹkunrẹrẹ itan aye rẹ wa ninu fidio yii...