You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Ghana Election Special Voters list 2020: Báyìí ni àwn òṣìṣẹ́ tó dá yàts ṣe ní ọjọ́ ìdìbò tiwọn lọ́tọ̀
Awọn ọlọpaa, ologun, oniroyin atawọn to n wa ọkọ agboku ni orilẹede Ghana ti wọn jẹ oṣiṣẹ akanṣe ti n dibo lonii ṣaaju ọjọ keje oṣu kejila ti idibo gangan yoo waye.
Akanṣe eto idibo yii ti aj eleto idibo orilẹ̀ede ghana ṣe agbekalẹ rẹ jẹ fun awọn oṣiṣẹ koṣeemani ti yoo maa ṣiṣẹ fun awọn ara Ghana lọjọ keje oṣu kejila ọdun yii.
Nkan bii oludibo 109,577 lo n dibo bayii jakejado orilẹede naa kaakiri igun bii mejila ti ajọ eleto idibo fun laṣẹ lati kọkọ dibo
eto idibo toni bẹr ni agogo meje owurọ eyi ti yoo si pari ni nkan bii ago marun irọlẹ oni.