Sickle Cell In Nigeria: Makinde ní ìgbàgbọ́ ninú ìdílé òun ṣèdíwọ́ láti ṣàyẹ̀wò ẹ̀jẹ̀
Ẹkọ ko pin si ibi kan, ojoojumọ si ni eeyan yoo maa kọ ẹkọ si nile aye.
Titilayo Makinde jẹ alarun foniku fọlande, ti oloyinbo n pe ni sickle cell laimọ titi to fi pe ẹni ọdun mejidinlogun.
Makinde ni ẹsin igbagbọ tawọn n sin nile awọn mu ko nira lati tete maa lọ sile iwosan, eyi si lo sediwọ fun awọn obi oun lati mọ nigba toun wa ni ọmọ ọwọ.
Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:
- Kí lo fẹ́ mọ̀ nípa ‘Ajala Travels’?
- Ṣẹ gbọ́ nípa Alájọ Ṣómólú, tó ta mọ́tò ra kẹ̀kẹ́?
- Ẹfunroye Tinubu - Ògbóǹtagí oníṣòwò, olówò ẹrú àti afọbajẹ
- Samuel Ajayi Crowther, òjíṣẹ́ Ọlọ́run tó gbé èdè Yoruba lárugẹ
- Mọrèmi Àjàṣorò, akọni obìnrin tó gba Ilé Ifẹ̀ sílẹ̀ lóko ẹrú
- Ọ̀rọ̀ǹpọ̀tọ̀niyùn, Aláàfin obìnrin àkọ́kọ́ rèé, tó ní nǹkan ọkùnrin
- Baṣọ̀run Gáà, tó yan ọba mẹ́rin, pa ọba mẹ́rin àmọ́ ọba karùn-ún ló pa á
Titilayo wa sọ nipa idẹyẹsi, abuku ati ijakulẹ ifẹ tawọn alarun naa maa n koju lawujọ ati iriri rẹ pẹlu.
Bakan naa ni ọkọ afẹsọna rẹ, Bamidele Toluwalase naa salaye fun BBC Yoruba nipa isoro to la kọja ki awọn obi rẹ to fi ọwọ pe ko fẹ Titilayo, tii se alarun sickle cell.