Blind DJ: Etu Omotayo kò ríran àmọ́ ó le to irinṣẹ́ eléré pọ̀ láti kọrin láì sí ìrànwọ́
Yoruba ni ba o ku, ise ko tan, ẹni to ba si ti ku laye, nikan ni tiẹ ti tan, nitori ireti si wa fun igi ti a bẹ lori.
Eyi ni a fi lee se apejuwe igbe aye ọgbẹni Etu Sodiq Omotayo ẹni to ni ipenija oju amọ to n sisẹ gbogbo elere lati wa ounjẹ oojọ jẹ.
Etu ni fasiti Ibadan ni oun wa bii akẹkọọ nigba ti oun ko riran mọ, to si dabi ẹni pe ọna ti pin fun oun sugbọn Ọlọrun la ọna lati ipasẹ isẹ gbogbo elere naa.
Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:
- A jọ ṣe ìyàwó pọ̀, a jọ bímọ ní ọjọ́ kan náà, a tún jọ máa ń ṣàìsàn pọ̀ ni
- Òkè Idanre rèé tí odidi ìlú kan ló ń gbé lórí ẹ̀
- Ìyàwó mi fẹ́ràn ìrìnàjò òfurufú ni mo ṣe kọ́ ilé Bàálù yìí fún un
- Omi ìṣẹ̀ńbáyé tó ń dà ní Ówù rèé, èyí tó ga jùlọ ní Afirika
- 'Ǹkan tó jẹ́ kí iṣẹ́ ọ̀nà tèmi yàtọ̀ lágbàáyé ni ǹkan tí mò ń lò'
- Mo ti sọ ìran nípa ọkọ aképo tó gbiná ní Onitsha kó tó ṣẹlẹ̀ - Primate Ayodele
- Àlá àwọn òjíṣẹ́ Olúwa tó fẹ́ jẹ ààrẹ Nàíjíríà leè má ṣẹ lógún ọdún - Abiara
Etu ni ọmọ mẹfa ni fasiti, ti ọkan yoku si wa nile ẹkọ girama, idi isẹ gbogbo elere, taa mọ si DJ yii si lo ti n ri owo gbọ bukata wọn.
O wa parọwa si awọn eeyan to wa ni iru ipo to wa yii ati awsn to n la ipenija miran kọja lati di opo Ọlọrun ọba mu.