Ṣe lilo Methtoletom lé koju aarun Corornavirus?

Àkọlé fídíò, Ṣe lilo Methtoletom lé koju aarun Corornavirus?

Laipe yii ni ààrẹ Guinea Alpha Condé ni ti eniyan ba lo mentholetom pẹlu ọmi gbigbona yoo bọ lọwọ ààrun Corornavirus.

Ko si ootọ ọrọ nínu ọrọ yìí nitori ko si àridaju imọ sayẹnsi to sọ pe eyi ri bẹẹ.

O se pataki ki tọkọtaya wa ní isọkn niru asiko yii, nítori pé ọna yii nikan ni aabo to yẹ yoo fi wa ninu idile