Fadeyi Oloro: Ọfọ̀, àyájọ́ kò ràn án lọ́jọ́ tí 'ṣó o láyà' bá a lálejò
Eto 'Ṣó o láyà' lati BBC News Yoruba ni eto ti a ti maa n gbe awọn ibeere nipa aṣa, ede, iṣe ati ọrọ to n lọ ni Yoruba ka iwaju awọn eekan oṣere.
Lọtẹ yii, ẹja nla ni awọn eto yii gbe lodo.
- Mi o tíì rí olórí tó fẹ́ràn Naijiria tó Baba Obasanjo- Yoruba Council of Elders
- Eyín mi ló lágbára jù ní Afíríkà, mò ń fi eyín gbé àpò ìrẹsì, símẹ́ńtì àti jẹnẹrátọ̀ - Taju eléyín idán
- Làá hàn mí dé, ètò tó ń ṣàlàyé ohun tó yẹ ká ṣe láti dènà àrùn Coronavirus
- Obìnrin tó ń ṣiṣẹ́ ẹrú ní Oman tó bá fẹ́ òmìnira, yóò bá ọ̀gá rẹ̀ ṣùn - obìnrin méjì tó ti oko ẹrú dé
- Kí ló le è mú kí ìlú kan ó já ọmọge mẹ́rin sí ìhòhò?
- Odunlade fẹ́ j'ọba, Bolanle Ninalowo fun ìyàwó rẹ̀ ni ẹ̀bun kanka, Pá Kasumu rebi àgbà ree
eekan oṣere tiata, Ọgbẹni Ojo Arowoṣafẹ, ti ọpọ mọ si Fadeyi oloro ni ọpọn sun kan.
Atogede, atayajọ ni baba fi dahun ibeere wa gbogbo.
Amọṣa, aigbọfa la n woke, ifa kan ko si ni para