You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Yoruba Language: Àwọn ọmọ Yorùbá fẹ́ràn orí ara wọn ju ìtumọ̀ ọ̀rọ̀ burúkú lọ
Ọ̀rọ̀ kìí tóbi títí ká fi ọ̀bẹ bù ú. Bí a bá jẹ́ ojúlówó ọmọ Yorùbá tí ìmọ̀ èdè wa sì dájú, bíi pé à ń fẹran jẹ̀kọ ló yẹ kí títúmọ̀ èdè Yorùbá jẹ́.
Bí kò bá wá rí bẹ́ẹ̀, ànfàní rèé láti bẹ̀rẹ̀ sí ní kọ́ èdè Yorùbá lórí bbc.com/yorùbá.
Ikọ iroyin BBC Yoruba jade lati tẹsiwaju ninu igbesẹ kikọ ati mimu wa si iranti awọn ọmọ Yoruba paapaa ju lọ awọn ọdọ pataki ede Yoruba.
Ẹwẹ, lati sọ itumọ "arinfẹsẹsi", oriṣiriṣi la ba bọ.
Ki Ọlọrun ma jẹ ki ẹyin olo9lufẹ BBC ṣe kongẹ laburu bi ko ṣe konge ire nigba gbogbo.