You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Aeroplane House: Látọdún 1999 ni mo ti bẹ̀rẹ̀ kíkọ́ ilé yìí fún ìyàwó mi ọ̀wọ́n
Said Jamal jẹ oniṣẹ ile kikọ.
O ni oun ti bẹrẹ ile to n kọ fun iyawo rẹ yii lati ọdun 1999. Yara kan lo kọkọ pari ti oun ati ẹbi rẹ si ko sinu ẹ titi ti wọn fi kọ ọ de ibi ti o de bayii. Koda ko ṣi tii pari.
Ni agbegbe Asokoro ni olu ilu orilẹede Naijiria, Abuja ni ile awoyanu nla yii kalẹ si.
- Awakọ̀ bàálù ológun òfurufú obìnrin àkọ́kọ́ ní Nàìjíríà rè e
- Obìnrin awakọ̀ Bàálù àkọ́kọ́ láti Ọffa rèé
- 'Ìdí tí pápákọ̀ ofurufú l'Ekiti kò fi m'ógbọ́n wá'
- Ààrẹ Mozambique tẹ́lẹ̀ rí jẹ́jọ́ lórí ẹ̀sùn ìwà ìbàjẹ́ tí wọ́n fi kan ọmọ rẹ̀
- Òní ní Oloye Christopher Adebayo Alao Akala yóò wọ káà ilẹ̀ lọ ní Ogbomoṣo
- Ẹnikẹ́ni tó bá tún fi ìyà jẹ òṣìṣẹ́ LASTMA l'Eko yóò fojú winá òfin- Ọ̀gá LASTMA
"Nigba ti mo fẹ iyawo mi, awọn obi rẹ sọ fun mi pe o fẹran lati maa rinrinajo". Eyi lohun ti Said sọ fun akọroyin BBC.
Liza Jammal ni iyawo Said. Ṣe loju maa n ti i ti ko si fẹran lati maa foju han tori naa, ọmọ rẹ ọkunrin to gbẹnu rẹ sọrọ Mohammed Jammal ti o gbajugbaja pẹlu orukọ rẹ, "White Nigerian" sọ bi wọn ṣe bẹrẹ ile naa.
- Yàtọ̀ sí Bimbo Success àti Kemi Korede, wo àwọn míì tí wọ́n ń pariwo Funke Akindele kiri
- Àwọn òṣìṣẹ́ wa kò lọ́wọ́ nínú gbígbé egbògi olóró - NDLEA
- Ǹjẹ́ ó mọ̀ nípa Álífábẹ́ẹ̀tì Oduduwa àti bí o ṣe lè lòó fi gbé èdè Yorùbá ga?
- Wo ọkùnrin kan tó fi N1.2m gbẹ́ ibojì rẹ̀ sílẹ̀ nígbà tó sì wà láàyè
- Ìjọba Canada ṣetán láti gbẹ́sẹ̀ lé àkáùntì àwọn tó ń ṣẹ ìwọ́de táko abẹ́rẹ́ covid-19
- Wo ohun tí ìjọba ṣe fún akẹ́kọ̀ọ́ kílààsì SS 2 tó gbá Olùkọ́ létí ní Ibadan
- Ẹ̀yin ará ìlú ẹ má bìnú, kìí ṣe pé a mọ̀ọ́mọ̀ kó epo tí kò dáa wọ Naijiria
mo rẹ tun ni pe: "lati ọmọ ọdun mejila ni mo ti gbọ́nju ba Baba mi to n kọ ile ọkọ baalu yii titi ti mo fi dagba bayii".
"Itan mi kii ṣe itan ifẹ nikan. bi ko ṣe kiko ipa". Eyi ni Said sọ.