You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Àwọn orílẹ̀-èdè tí ààrẹ Buhari ti lọ láàrin ọdún márun
- Author, Usman Minjibir
- Role, BBC Hausa
Àwọn ǹkan to tí n dá awuyewuye sílẹ̀ júlọ láàrin ọjọ mẹta yiìí yála lóri ayélujara tàbi láarin àwọin ènìyàn ni pé ààrẹ Muhammadu Buhari rìnrinnàjọ lọ si orilẹ̀ -èdè Saudi Arabia láti ṣe ìpádé àpérò lórí ọ̀rọ̀ ajé Nàìjíríà fún ọjọ iwáju, ti o si tí ìbẹ̀ ré si ilú London titi ti yóò fi di ọjọ kẹtadinlogún osù yìí ko to dari wále.
Ọjọ́ sátide ni ààrẹ kúrò ni Saudi Arabia lo sí ilẹ̀ Gẹẹsì níbi ti yóò ti lo ọjọ mẹ́tàdinlogun lori ǹkan ti kò niṣe pẹ̀lú orilẹ̀-èdè Naijiria
Tí ààrẹ ba wá de ni ọjọ kẹtadinlogun osù yìí, o túmọ si pé àláṣẹ káàfàta, ajagun fẹ̀yìnti Buhari ti lo irinwo ọjọ́ àti marundinlọgbọ̀n (ọdun kan àti osu meji) nílẹ̀ okere láàrin ọdun marun to ti di ààrẹ.
BBC ṣe ìwádìí nínú àkọsílẹ̀ rẹ̀ bákan náà ló lo ìròyìn ti Daily Trust ko jọ, nípa ìrìn ajo ààrẹ àti iye ọjọ to lò ni ilú okere láti igba to ti de Aso Rock
2015
- 3rd July (Niamey Niger) Ìpàdé lori ọ̀rọ̀ Boko Haram ni ọsẹ kan lẹ́yìn to bura wọle.
- 4th July Ndjamena Chad- Ìbẹwo fun ilọsiwáju orilẹ̀-èdè
- 7-8 July Germany- Honour G7 Wọ́n fiwe pe ààrẹ ati àwọn orilẹ̀-èdè míràn
- 12-13 July South Africa- lati kopa nínú àpero AU ẹlẹkẹdọ́gbọ̀n irú rẹ̀
- 19-23 July Washington-Ìbẹwo fun ilọsiwáju orilẹ̀-èdè
- 29-30 July Yaounde Cameroon- Ìbẹwo fun ilọsiwáju orilẹ̀-èdè
- 2-3 August Cotonou O lọ kopa ninu àyẹyẹ ominira orílẹ̀-èdè náà
- 7 September Accra Ghana Ìbẹwo fun ilọsiwáju orilẹ̀-èdè
- 14-16 September Paris France Ìbẹwo fun ilọsiwáju orilẹ̀-èdè
- 24-29 September New York United Nations Assembly Àádọ́rin irú rẹ̀
- 26-30th October- New Delhi India-Apero lori ọ̀rọ̀ ilẹ adúláwọ(Africa Summit)
- 22-24 November Tehran Iran- Ipade awọn orilẹ̀-èdè tó ni epo àti afẹ́fẹ́ gáàsì
- 30th November Paris- Ìpáde awọn ẹgbẹ́ to yawo Paris
- 4-5 December Johannesburg- Àpero láàrin China ati Afirika
- 10th December Benin Republic- Isinku ààrẹ Kerekou
2016
- 8 January Benin- Ìpáde àwọn ti odo Niger sopọ, ikọkanla irú rẹ̀
- 17-20 January Abu Dhabi UAE- Ipade lori ríra àwọn ohun ija ọlọro
- 26 January Addis Ababa- Ipade àwọn olori orilẹ̀-èdè ẹlẹkẹrindinlọ́gbọ̀n irú rẹ̀
- 27-29 January Nairobi Kenya Ìbẹwo fun ilọsiwáju orilẹ̀-èdè
- 2-4 February Strasbourg France Ìbẹwo fun ilọsiwáju orilẹ̀-èdè
- 5-10 Feb London Isinmi
- 18 Feb Egypt -ìpàdé ilẹ̀ Afikrika tọdun 2016
- 22-27 Feb Mecca, Saudi Arabia- Ìbẹwo fun ilọsiwáju orilẹ̀-èdè
- 27-28 Feb Doha, Qatar Ìpáde OPEC
- 14 March Equatorial Guinea Ìbẹwo fun ilọsiwáju orilẹ̀-èdè
- 30th March Washington- Ipade lori ǹkan ija oloro
- 11-14 April Beijin China Ìbẹwo fun ilọsiwáju orilẹ̀-èdè
- 13-15 May London Ìpade láti gbogun ti gbigba abẹtẹl àgbáye àti iwa ajẹbanu
- 6-19 July London - Isinmi nítori o sàìsàn
- 8 August Chad Ibúrawole fun ààrẹ Idris Deby
- 27-28 August Nairobi Kenya- Tokyo gathering on Africa Ipade ile Adulawo ni Tokyo
- 13-16 October Germany Ìbẹwo fun ilọsiwáju orilẹ̀-èdè
- 14-18 November Marrakech Morroco-Ipadae isokan agbaye lori ayipada oju ọjọ
- 5-7 December Senegal Ipade apapọ lori mimu aláfia wa si ilẹ Adulawọ
- 13 December Gambia Ipade ECOWAS
2017
- 7 January Accra Ghana- Iburawolẹààrẹ Nana Akufo ti Ghana
- 12 January Gambia Ipade alafia awon orilede ECOWAS
- 13-14 January Mali France- Apero ilẹ Adulawọ
- 19 January-30th March London Gab aye isinmi àti toju aisan to n ba fira
- 7th May - 13th August London Irinjo lati lo toju ara rẹ fun aisan
- 17-21 September New York UN General Assembly ẹlẹkejiléláàdọrin
- 21-25th Sept London O gabaaye isinmi
- 18-22nd October Turkey- Ìbẹwo fun ilọsiwáju orilẹ̀-èdè àti ipade àwọn orilẹ̀-èdè ti o ti tojuubọ
- 24th October Niamey Niger, Ipade ECOWASlori lilo owo kan naa nilẹ Afirika
- 28th November Abidjan Ivory Coast- 5th Ipade EU fun ilẹ Afirika
- 11 December Paris France Ipade lori iyipada oju ọjọ
- 18 December Niamey Niger, Abẹwo la'ti ṣe ayẹyẹ igbominira élékókandinlọgọta irú rẹ
2018
- 26-30th January Ethiopia t Ipade awọn olori ilẹ Adulawo ti AU ọgbọ̀n iru rẹ
- 5th March ayẹyẹ ominira orílẹ̀-ède Ghana
- 9-19 April London Ipade awọn orilẹ-ede Commonwealth
- 28-30th April Washington Ìbẹwo fun ilọsiwáju orilẹ̀-èdè
- 1-2 May London o kọja lo si orilẹ̀-ede miran
- 8-18 May Londonlati lori onisegun
- 10-12 June Morocco Ìbẹwo fun ilọsiwáju orilẹ̀-èdè
- 30 June 2 July Mauritania-Ipade EU ni Africa
- 15-18 July Netherlands Ipade lati fẹniu ọ̀rọ̀ jón lori ilé ẹjọ agbaye
- 29-30 July Lome Togo Ipade àwọn olorin orilẹ̀-ede to wa ni ECOWAS
- 3-13 August London O lọ fun isimi
- 31 Aug-3rd Sept Ipade láàrin China ati Africa
- 23-27 September New York UN General Assembly
- 9 November France- Ipade awon to gba owo Paris
- 23 November Chad Ipade lori ọ̀rọ̀ Boko Haram
- 2-3 December Poland Ìbẹwo fun ilọsiwáju orilẹ̀-èdè
2019
- 1 April Senega - Iburawọle fún ààrẹ Macky Sall
- 4-6 April Jordan Ipade lati mu idagbasoke ba ọrọ aje àwọn orilẹ̀-èdè Afirika
- 7-11 April 9th Ipade Idokoow ti Dubai
- 13 Apr Chad Ipade awọn orilẹ̀-èdè to ni isoro ọgbẹlẹ
- 25 Apr -5 May London O gbaye fun isinmi
- 15 May -5 June Saudi Arabia O lọ fun Imura
- 30 June- 2 July Ipade awon orilẹde to jẹ ti Islam
- 6 July- Niamey Ipade Eu lori dida ile isẹ silẹ̀
- 26 July Liberia Ayẹyẹ ọdun ominira
- 25-30 Aug Japan meeting on Japan-Ipade ibasepọ láàrin Japan àti awọn orilẹ̀-èdè Afrika
- 14 Sept Burkina Faso Ipade ECOWAS lori ọ̀rọ̀ igbesumọmi
- 25 Sept - Oct 1 New York Ìbẹwo fun ilọsiwáju orilẹ̀-èdè
- 2-3 South Africa Ìbẹwo fun ilọsiwáju orilẹ̀-èdè
- 21-23 Oct Sochi Russia
- 28-31st October Ìpade pẹlu Saudi Arabia lori idokoowo
- 31-17 November Abẹwo ti ko niṣe pẹ̀lú ọ̀rọ̀ ìlú
Tí a ba wo alaye yìí fínifini à o ri pé ọdun kan ati osu meji ni ààrẹ Buhari ko fi si ni ọfíìsì rẹ̀ ni Naijiaria.
Eyi lo mu ki àwọn ẹka ènìyàn meji maa sọ̀rọ̀ nipa irinajo ààrẹ, àwọn to faramọ irinajo náà àti àwọn ti wan n wo pe ko yẹ ko ri bẹ́ẹ̀ nitori ko ni ipa kankan fun ilọsiwaju Naijiria.
Aríyànjiyan yìí bẹ́rẹ̀ lẹ́yin ti agbẹnusọ ẹgbẹ́ alátako ni Naijiria Ibrahim Tsauri sọ pé gbogbo irinajo à[rẹ ko ni nkan se pẹlu ilọsoiwaju Naijiria
Sùgbọ́n ilé iṣẹ́ à[rẹ sàlàyé pé àwọn ìrìn ti ààrẹ n ri yìí ṣe patàki fún Naijiria ati ọ̀rs aje rẹ̀
Onimọ nipa ètò òṣèlú Abubakar Kari ti fasiti Abuja sàlàyé pé ìrìnajo ààré ní iṣẹ to pọ láti ṣe fun ibásepọ pẹlu orilẹ̀-èdè mírà àti ètò ọ̀rs aje Naijiria.
But the University man add say " di problem wey dey dia be say up till now poor Nigerians dey say dem neva see anything on ground upon all di
O wá fi kún pé " isoro to wa nibẹ pé àwọn otosi Naijiria o ti ri eso rere kankan ti ìrìnajo náà ti so"