Isheri Flood: Àwọn olùgbé Isheri ń sanwó fún ọkọ̀ ojú omi láti rìn ní àdúgbò

Àkọlé fídíò, Isheri Flood: Àwọn olùgbé Isheri ń sanwó fún ọkọ̀ ojú omi láti rìn ní àdúgbò

Ẹ̀kún omi lé ọ̀pọ̀ onílé ní àdúgbò Isheri ní Eko.

Àwọn olùgbé Isheri yii si lo n sanwó fún ọkọ̀ ojú omi láti rìn ní àdúgbò.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

Iroyin naa ni adagun omi Ogun-Osun ti wọn n si lo sokunfa ẹkun omi naa, to maa n waye lọdọọdun.

Koda, ileesẹ amunawa ti pa ina to lọ si adugbo Isheri nitori ẹkun omi.