You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Léyìn òpọ̀lọ̀pò ọdún àgbàọ̀jẹ̀ agbábọ́ọ̀lù ọmọ Cameroun ní òun ti dé wáàsimi
Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 1
Gbajugbaja agbabọọlu ọmọ ẹgbẹ Barcelona ati Inter Milan, Samuel Eto o ti ṣalaye pe oun ko gba bọọlu mọ.
Etoo to jẹ ọmọ ọdun mejidinlogoji ṣalaye lori ẹrọ ayelujara rẹ pe asiko ti to fun oun lati feyinti sinmi ninu are boolu.
- Alexis Sanchez: Mí o kabamọ ìgbà tí mo ló ní Man United
- Àwọn akọni Nàìjíríà padà sílé pẹ̀lú àmì ẹ̀yẹ 121 láti Morocco
- Ìjà orogún méjì ní London, Arsenal àti Tottenham ta ọ̀mì
- Ẹgbé agbábóólù orílẹ-èdè Naìjíríà gba ẹbuǹ wúrà ilẹ Afrika
- Van Dijk gbadé UEFA mọ́ Messi àti Ronaldo lọ́wọ́
- Liverpool kun Arsenal wẹ́lẹ́wẹ́lẹ́ bí ẹran àsun 'lójúbọ' Anfield
Eto o ọmọ bibi ile Cameroon ti o si ti wa lẹnu boolu gbigba lati bii ọdun mejilelogun.
Ogunna gbongbo ninu are bọọlu yii ti mu igbega ati idagbasoke ba bọọlu gbigba ni ilẹ Afrika lati ọdun 1997 ti o ti bẹrẹ.
O gba ife ẹye ti ilẹ Afrika ni ọdun 2000,2002 ati Champions liigi fun ọdun 2006,2009 ati 2010.