Buhari yóò rí ara rẹ̀ gẹ́gẹ́ bíi Mèsáyà yóò sì gbìmọ̀ràn sáà kẹta nípò-Dele Momodu
Odu oniroyin ni Dele Momodu ti ẹnikẹni ko le jiyan lori iduro rẹ gẹgẹ bi ajafẹtọ araalu pẹlu.
- MKO Abiola, iṣẹ́ aṣẹ́gità ló fi bẹ̀rẹ̀ okoòwò
- ‘Buhari kìí fá orí apákan, dá apakan sí’
- Ìjọba Nàìjíríà gbọdọ̀ ṣàlàyé ìdí tí 13.2m ọmọdé kò ṣe lọ sílé ẹ̀kọ́ - SERAP ké tọ iléẹjọ́ àgbáyé
- Ọrọ̀ ajé Nàíjíríà tún leè dagun tí Buhari bá fi ìyànsípò àwọn mínísítà falẹ̀ si - Onímọ̀
- A óò wá àwọn ọmọ ilẹ̀ Turkey mẹ́rin tí wọ́n jígbé rí láàyè- Ọlọ́pàá Kwara
Amọṣa lasiko idibo apapọ to kọja, ọpọ awọn ọmọ orilẹede yii paapaajulọ awọn to jẹ alatilẹyin Aarẹ Muhammadu Buhari ni wọn kọju ija sii lori ọpọ oju opo ayelujara wi pe o n tẹle oludije fun ẹgbẹ oṣelu PDP lasiko idibo naa, oloye Atiku Abubakar.
Bi o tilẹ jẹ wi pe idibo apapọ ti lọ, sibẹ Dele Mọmọdu ni ironu awọn eeyan to wa nidi eyi ba oun ninu jẹ lọpọlọpọ, o si mu ẹnu le alaye ninu ifọrọwanilẹnuwo yii pẹlu BBC News Yoruba.