Yoruba Proverbs: Mélòó lo lè parí nínú òwe Yorùbá yìí?

Ọpọ ọmọ Yoruba lo maa n leri pe awọn dantọ ninu imọ ijinlẹ ede Yoruba ati nipa aṣa ibilẹ wa.

Lara ohun ti eeyan le fi danrawo boya lootọ ni aayan mọ ijinlẹ ede Yoruba niyii, a ti ṣe akojọpọ diẹ lara awọn òwe ti BBC Yorùbá ti lò sẹyin fun yin.

Bi o ba wa da ọ loju pe o mọ owe Yoruba, tẹ ibi yii ki o dahun bi o ṣe yẹ.

O ni anfani lati wo maaki rẹ bi o ba ṣe tan.

Awọn Iroyin mii ti ẹ le nifẹ si