Seyi Makinde: Màá fẹ́ káwọn aráàlú mọ ìpa ìjọba mi lára sí rere

Àkọlé fídíò, Seyi Makinde: Màá fẹ́ káwọn aráàlú mọ ìpa ìjọba mi lára sí rere

Oludije fẹgbẹ oselu PDP fun ipo gomina ipinlẹ Ọyọ, Onimọ ẹrọ Seyi Makinde ti kede pe orisirisi nkan ni ẹni to ba n wa nkan yoo maa sọ, amọ ni ti oun, awọn nkan ti oun fẹ gbe se fun ara ilu ni oun n fọn rere rẹ.

Makinde ni awọn ara ilu yoo mọ ipa isejọba oun lara si rere ti oun ba gori aleefa, ti wọn yoo si mọ iyi oun ti oun ba pari isejọba oun.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

O ni ohun to yẹ ki gomina ipinlẹ Ọyọ lọwọlọwọ bayii maa se ni ijiyin isẹ iriju rẹ lati ọdun mẹjọ sẹyin, amọ dipo bẹẹ, ẹẹkẹ eebu lo n se.