2019 Nigeria Budget: Wo pàsán ojú Buhari tó dá awuyewuye sílẹ

Oríṣun àwòrán, Channels TV
Lọjọru ni Aarẹ orileede Naijiria Buhari lewaju awọn ọmọ igbimọ rẹ lo ṣe agbekalẹ abadofin isuna ọdun 2019 ṣugbọn oun ti awọn asofin ṣe fun lawọn eeyan n sọrọ nipa rẹ.
Awọn asofin lati ẹgbẹ APC to wa lori ijọba ati awọn akẹgbẹ wọn lati ẹgbẹ PDP ko fun ara wọn ni ọrọ sọ nigba ti Aarẹ Buhari n bawọn sọrọ.
Awọn alatilẹyin rẹ n ke dansaaki rẹ ti awọn alatakọ si n ṣe ọọbi fun un.
Bi Aarẹ Buhari ti ṣe n mẹnu ba awọn akanṣe iṣẹ ti ijọba rẹ ti gbeṣe ni 2018 ni asofin kan ti a ko ri oju rẹ bẹrẹ si ni pariwo ''irọ ni,kii ṣe ootọ
Ohun ọkunrin naa gbalẹ debi wi pe Aarẹ Buhari gbọ ohun to so ti o si danuduro lati wo ẹni to sọ ọrọ naa.
Awọn ọmọ Naijiria ṣe akiyesi bi Buhari ti ṣe na ẹni naa ni pasan ọju ti wọn si fi iriwisi ọtọọtọ sita lori nnkan to fa.
Ẹyin naa ẹ wo fọnran fidio naa:
This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.
End of X post, 1
Ati awọn iriwisi to tele
This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.
End of X post, 2

End of X post, 3

End of X post, 4